UNESCO

Ile-iṣẹ pataki ti United Nations fun eto-ẹkọ, imọ-jinlẹ, ati asa

UNESCO dúró fún United Nations Educational, Scientific and Cultural Organization ní èdè Gẹ̀ẹ́sì (Àjọ Ẹ̀kọ́, Sáyẹ́ńsì àti Àṣà tí Ìṣọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè)


United Nations Educational, Scientific and Cultural Organization
IrúSpecialized Agency
OrúkọkúkúrúUNESCO
OlóríFránsì Audrey Azoulay
IpòActive
Dídásílẹ̀November 16, 1945
IbùjókòóParis, France
Ibiìtakùnwww.unesco.org

Wọ́n dá UNESCO sílẹ̀ ní ọdún 1945 lẹ́yìn League of Nations' International Committee on Intellectual Cooperation.[1] Àwọn àjọ òǹdásílẹ́ UNESCO, ní èyí tí ó wáyé nípa ìṣẹ̀lẹ̀ World War II, láti mú ìtẹ̀síwájú àlàáfíà, ìdàgbàsókè tó yanrantí àti ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn nípa mímú ìbáṣepọ̀ àti ìfọ̀rọ̀jomitoro-ọ̀rọ̀ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.